Aare egbe akoroyin nile wa Oloye Chris Iziguzo ti bu enu ate lu oro iroyin ti o lese nle nile wa.
O soro naa nibi ayajo to nsami ayeye ojo iroyin l’agbaye nilu Abuja.
Oloye Iziguzo se l’alaye je ohun to npa igi di’na idagbasoke ise iroyin.
O fikun pe iwadi ti so di mimo pea won ti kii se omo egbe oniroyin ni aje iwa ibaje yi nsi mo lori.
O wa kesi ijoba ati awon to ni nkan se nidi ise iroyin lati pawopo gbogunti iwa yi ki ise iroyin le maa goke si.
Kemi Ogunkola/Morenike Esan