Home Posts tagged Alhaji Abbas Idris
Yoruba

Ilé Tó Dàwó Sekúpa Ẹnìkan Nílu Abuja

Apákan ilé alájàméjì tí wọ́n ńkọ́ lọ́wọ́ nílu Abuja ti dàwó pẹ̀lú olùgbé kan nínú ilé náà tó jọ́lọ́hun nípè. Ilé ọ̀hún tó dàwó lówà lẹ́yìn Cites Estate lójú ọ̀nà pápákọ̀ òfurufú ní Jabi. Ìsẹ̀lẹ̀ náà, gẹ́gẹ́bí ọ̀gá àgbà àjọ tó ń mójútó ìsẹ̀lẹ̀ pàjáwìrì ẹkùn Abuja, Àlhájì Abbas Idris sewi, ló Continue Reading