Home Posts tagged Arábìnrin Ibukunoluwa Otesile
Yoruba

Onímọ̀ Nípa Ètò Àwọn Ọmọdé Bèèrè Fún Ìfọwọ́sowọ́pọ̀ Lórí Àbò Àwọn Ògo Wẹẹrẹ

Ajáfẹ́tọ ọmọdé kan títúnse olùdarí àjọ Hope for Second chance Foundation, HOSEC, Arábìnrin Ibukunoluwa Otesile, ti bèèrè fún ìdí tó fi sepàtàkì fáwọn èèyàn àwùjọ láti máà sọ̀rọ̀jadé nígbà tí wọ́n bá ńfojú ẹ̀tọ́ àwọn ọmọdé gbolẹ̀. Arábìnrin Otẹsile fìdí èyí múlẹ̀ lákokò tón bálesẹ́ wa sọ̀rọ̀ Continue Reading