Home Posts tagged àwọn ọmọ ológun
Yoruba

Ìgbìmọ̀ tón rísí owó ìfẹ̀yìntì àwọn ọmọ ológun bèrè àtìlẹyìn lórí àfikún owó ìsúná

Àjọ tón bójútó owó ìfẹ̀yìntì àwọn ọmọ ológun, ti rawọ́ ẹ̀bẹ̀ sílé ìgbìmọ̀ asòfin àgbà láti fikun àbá ìsúná wọn kí wọ́n lè sanwó òsìsẹ́ fẹ̀yìntì ilẹ̀ yí lẹ́ka ilésẹ́ ológun. Alága àjọ ọ̀hún, ọ̀gbẹ́ni Saburi Lawal ló rawọ́ ẹ̀bẹ̀ yí nílu Abuja lásìkò tó wá síwájú ilé. Gẹ́gẹ́bí alága se wí, àjọ náà Continue Reading