Gbaju-Gbaja akewi n ni, Ojogbon Niyi Osundare, ti pe fun, ifowosowopo laarin awon, onkotan, ajafeto omoniyan, atawon asofin nidi igbese lati gbogun ti sise ayika nisekuse.
Ojogbon Osundare to soro yii nibi ipade apero kan, tokasi pe sise ayika nisekuse ti sokunfa oniruru isele ijamba lagbaye bi ile riri, biba oju ojo je, biba omi je, ati be be lo.
O tokasi pe igbese awon asofin nidi wiwa ojutuu si ayipada oju ojo, salaye pe ise awon onkotan naa yoo nise pupo lati se tawon asofin ba sisepo pelu won.
Ojogbon Osundare w ape fun igbese fifan rere ati ilaniloye ayika nipase isee.
Oyewumi Agunbiade/Elizabeth Idogbe