Home Posts tagged ètò ẹ̀kọ́
Yoruba

Àwọn onímọ̀ nípa ètò ẹ̀kọ́ gbàjọba níyànjú lórí bétò ẹ̀kọ́ kíkọ́ yo se rọrùn

Àwọn onímọ̀ nípa ètò ẹ̀kọ́ ti sọpé, ó se pàtàkì fún ìjọba láti pèsè àwọn ǹkan amáyédẹrùn èyí tí yóò mú kétò ẹ̀kọ́ kíkọ́ máà ja fafasi lákoko àtilẹyin àrùn covid-19. Lákokò tíwọ́n ń kópa lórí ètò ilé-isẹ́ Radio Nigeria kan lédè gẹ́ẹ̀si, tapeni Focal point, niwọn fìdí èyí múlẹ̀ nípa yàra ìkàwé, Continue Reading