Home Posts tagged Eto Idibo
Yoruba

Àjọ ẹ̀sọ́ alábo fi nomba pàjáwìrì síta fétò ìdìbò ìjọba ìbílẹ̀ ipinle Oyo

Àjọ àbò ara ẹni láàbò ìlú, NSCDC, ti fàwọn òsìsẹ́ àjọ náà ẹgbẹ̀rúnméjìlélẹ́gbẹ̀rin sọwọ́, fún ètò ìdìbò ìjọba ìbílẹ̀ tí yóò wáyé lọ́jọ́ àbámẹ̀ta ọjọ́ kejìlélógún osù larun ọdún yíì nípinlẹ̀ ọ̀yọ́. Ọga àgbà àjọ NSCDC nípinlẹ̀ ọ̀yọ́, ogbẹ́ni Iskilu Akinsanya sọ èyí lólú-ìlú ilésẹ́ náà, Agodi Continue Reading