Home Posts tagged Fọla Akinọsun
News Yoruba

Olósèlú Tó Jẹ́ Ọmọbíbí Ilẹ̀ Bàdàn Sọ Pé Ìlànà Àtúntò Ìsèjọba Àpapọ̀ Yo Wójùtú Sí Ìpèníjà Tón Kojú Ilẹ̀ Nàijírìa

Ìlànà àtúntò ètò ìsèjọba àpapọ̀, ni ọ̀nà kan gbóògi láti fi wá ojútu sí ìpèníjà tón kojú ill Nàijírìa. Ọrọ yí ló tẹnuma olósèlú tó jẹ́ ọmọbíbí ilẹ̀ bàdàn, ọ̀mọ̀wé Fọla Akinọsun jáde nínú ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò pẹ̀lú akọ̀ròyìn ilésẹ́ Radio Nigeria. Ọmọwe Akinọsun sọ ìdí pàtàkì tó fi yẹ kí ìlànà Continue Reading