Yoruba

Iko awo oluwadi to je akose mose, eyiti Aare tele f’orileede Ireland, Mary Robinson lewaju ti ile adari ile ifowopamo idagbasoke ile Africa yan kankan nidi iwa ajebanu ti wonfikan.

Iko eleni meta naa, eyiti Arabinrin Robinson lewaju ni Adajo Agba Ile Gambia, Hassan Jallow, ati igbakeji Aare iko to nrisi iduroore banki agbaye, Leonard Mccarthy kosodi s’ope Omowe Akinwumi Adesina we yan kankan l’owo awon esun tawon asinjoba nigbere ipako fikan.

Omowe Adesina, na wo fesun oniruuru kan leyin ti esun awon olusin joba nigbere ipako jo sita sori afefe losu kerin.

Alakoso tele lorileede Nigeria naa lo ti ma nfi igbagbogbo sope ohun omowo mese ninu awon esun tiwon ti ka noun.

Elizabeth Idogbe