Home Posts tagged Ìjọba ìpínlẹ̀ Èkó
Yoruba

Ìjọba ìpínlẹ̀ Èkó bẹ̀bẹ̀ fún ìgbọ́raẹniyé lórí owó ẹnu ìloro Lẹ́kkí

Ìjọba ìpínlẹ̀ Èkó ti pàrọwà fáwọn onímọ̀tó láti ní ẹ̀mí ìgbọ́raẹniyé lórí bí wọ́n tise ńgberò àti bẹ́ẹ̀rẹ̀ síì gbowó padà lẹ́nu ìloro Lẹ́kkí. Alákoso fọ́rọ̀ ìròyìn nípinlẹ̀ Èkó ọ̀gbẹ́ni Gbenga Ọmọtọsọ ló pàrọwà yí nílu Èkó. Ọgbẹni Ọmọtọsọ tẹnumọ́ ìdí tí àwọn olùgbé ìpínlẹ̀ Èkó fi gbọdọ̀ máà Continue Reading