Home Posts tagged keresimesi
Yoruba

Ìgbìmọ̀ amúsẹ́yá ìjọba àpapọ̀ farun covid-19 pèfún sísọ́rase lákokò ọdún kérésìmesì

Ìgbìmọ̀ amúsẹ́yá ìjọba àpapọ̀ fárùn covid-19 rọ àwọn èèyàn ilẹ̀ yíì láti sọdún kérésìmesì àti ìsinmi ọdún titun bótiyẹ. Alága ìgbìmọ̀ náà títún se akọ̀wé ìjọba àpapọ̀ ọ̀gbẹ́ni Boss Mustapha ló sọ̀rọ̀ yíì nínú àtàjáde nílu Abuja. Ọgbẹni Mustapha níì ó se pàtàkì, káwọn èèyàn mú ìgbésẹ̀ àbò wọn Continue Reading