Awon omo ile Nigeria ti kesi ijoba apapo ati ajo elepo robi NNPC pelu gbogbo awon toro kan leka epo robi ati afefe gaasi pe ki won rii daju pe epo petirolu po yannturu fun lilo araalu. Won foju oro yi lede lasiko ti akoroyin Radio Nigeria n to pinpin ibi ti inkan de duro […]Continue Reading