

Igbakeji aare , ojogbon Yemi Osinbajo ti fi ireti han wipe orile ede Naijiria losi wa loju ona toto lori didari oro aje gba ibomiran nipa tenpele mo awon oja ti won nko lo ile okeere ti ko ni nknakan se pelu epo robi eyiyi ajo tonrisi oro kiko oja lo ile okeere nile yi NEPC sagbateru re.Ojoogbon Osinbajo soro yi nigbati o gbaalejo iko kan lati inu ajo NEPC eyiyi oga agba ajo naa to nfipo sile, Ogbeni Segub Awolowo ko sodi.O wa pe awon torokan leka naa lati jigir si awon ipenija to nbo lona nitori awon odun tonbo ni yio dan ile yi wo lori ipinnu re lati dari oro aje gba ibomiran.Ninu oro re, Ogbeni Segun Awolow slaye bi nkan to se nlo lori eto fife kiko oja lo ile okeere loju, eyiyi o nio se pataki fun didari oro aje ile yi gba ibomiran ti ijoba apapo to wa tenumo pelu awon elo ajo naa, ile yi lo wa loju ona ati mu idagbasoke ba eka ti kiise loju ona ati mu idagbasoke ba eka ti kiise tepo robi ko sai ro awon torokan lati mase kaare ninu akitiyan won .
Ayodele Olaopa