Home Posts tagged Àpò Ẹ̀fọn
News Yoruba

Ìjọba Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ Sèlérí Láti Pín Àwọn Àpò Ẹ̀fọn Fáràlú

Ìjọba ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ ti sèlérí láti pín àwọn àpò ẹ̀fọn tó n gbà látọ̀dọ̀ àjọ ilẹ̀ Amẹrica tón rí ìdàgbàsókè àgbáyé. Gómìnà Seyi Makinde ẹnití igbákejì olórí òsìsẹ́ fún Gómìnà, ọ̀gbẹ́ni Abdulmojeed Mogbọnjubọla ló jẹ́jẹ yíì lákokò tón tẹ́wọ́gba milliọnu márun àwọn àpò ẹ̀fọn látọ̀dọ̀ àjọ shún. Continue Reading