Home Posts tagged ayewo oju ofe
Yoruba

Ìjọba ìpínlè Ogun sàgbékalè ètò ayẹwo ojú ọ̀fẹ́ fáwọn onimoto

Àjọ ton mojuto idagbasoke eto ìlera alabode nipinle Ogun pẹ̀lú ifowosowopo ìgbìmò tó ń risi ọrọ ìlera ojú nipinle náà tí sàgbékalè ètò ayẹwo ojú lofe fáwọn onimoto, ero àtàwọn aladani láwọn ibùdóko jákèjádò ìpínlè náà gẹ́gẹ́bí ara eto ton sàmìń ayajo ọjọ́ iriran tóko lọ́dún yi. Nígbà tó ń Continue Reading