
Gbaju-Gbaja akewi n ni, Ojogbon Niyi Osundare, ti pe fun, ifowosowopo laarin awon, onkotan, ajafeto omoniyan, atawon asofin nidi igbese lati gbogun ti sise ayika nisekuse. Ojogbon Osundare to soro yii nibi ipade apero kan, tokasi pe sise ayika nisekuse ti sokunfa oniruru isele ijamba lagbaye bi ile riri, biba oju ojo je, biba omi […]Read More...