Home Posts tagged Cotonou
Yoruba

Ìjọba àpapọ̀ ti ní kòsí ìkọlù sílé asojú ilẹ̀ yi ní Cotonou

Iléésẹ́ tó ń bójútó ọ̀rọ̀ ilẹ̀ òkèèrè ti sọ pé, irọ́ funfun báláu ni fọ́rán àwòrán kan tó wà lójú òpó ẹ̀rọ ayélúgára, èyí tó ń sàfinhàn bí àwọn kan se lọ sèkọlù sí ilé asojú ilẹ̀ Nàijírìa tó wà nílu Cotonou, lórílẹ̀dè Benin. Agbẹnusọ fún iléésẹ́ nà, Ferdinand Nwaye, sọ pé fọ́rán àwòrán nà, […]Continue Reading