-
Ijoba Apapo, Ti So Pe, Aheso Oro Lasan Ni Pe Aarun Romolapo-Romolese Bee Sile
Ijoba apapo ti so pe ko si ooto ninu iroyin to n ja rohinrohin pe aarun romolapa romolese ti be sile lawon ipinle kookan. Ijoba fowo idaniloju re soya pe ko ti si isele aarun naa tuntun nile yi lati odun 2016. Ogaagba eto idagbasoke ilera alabode, Dokita Faisal Shuaib eni to ni ko si…
-
Ajo To N Risi Oro Ile Iwosan Alabode So Pe Kosi Aarun Romolapa-Romolese Ni Nigeria Mo
Laifi ti iroyin to n ja rain-rain pe aisan ko to farape romolapa romolese ti ja lawon apa ibikan nile yii se akosile to sope kosi aisan romolapa romolese mo nile yi si wa digbi. Oga Agba Ajo to nrisi ile-iwosan alabode nile yii, Dokita Faisal Shuaib so fawon oniroyin nilu Abuja wipe, ijoba tiko…