Awon elesin abalaye nipinle Oyo ti gbosuba fun, Gomina Ipinle Osun Ogbeni Gboyega Oyetola lori igbese kikede isinmi lenuse lati samin ayajo ojo isese nipinle. Ninu atejade eyi ti alaga egbe awon elesin abalaye teka ipinle Oyo Ogbeni Adefabi Fadiran ati akowe, omowe Fakayode Fatunde fisita nilu Continue Reading