Home Posts tagged ètò kólẹ̀kódọ̀tí
Yoruba

Aráalu gbósùbà fúnjọba lórí ètò kólẹ̀kódọ̀tí ọlọ́sẹ̀sẹ̀

Àwọn olùgbé ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ ti kan sárá síjọba lórí àsẹ tuntun nípa sísọ ètò kólẹ̀kódọ̀tí olósosù di ọlọ́sẹ̀sẹ̀. Wọ́n gbósùbà yi lásìkò ìfọ̀rọ̀wérọ̀ pẹ̀lú akọ̀ròyìn Radio Nigeria tó tọpinpin báwọn èèyàn se tẹ̀lé àsẹ náà si. Wọ́n tún rọ àwọn rọ àwọn aráalu pé kí wọ́n mú ìmọ́tótó àyíká wọn Continue Reading