Gómìnà ìpínlẹ̀ ọ̀sun, ọ̀gbẹ́ni Adegboyega Oyetọla, ti síjú áànu wo àwọn ẹlẹ́wọ̀n mọ́kànlá tó wá láwọn ibùdó àtúnse ìlú Ilésà àti Ilé-Ifẹ, tó sì dáwọn sílẹ̀. Gómìnà Oyetọla tó sanwó ìtanràn àwọn ẹlẹ́wọ̀n mọ́kànla náà lákokò àyẹ̀wò tó gbópọn lórí ẹ̀sùn wọn, sọ pé, ìgbésẹ̀ náà wáyé láti mú àdínkù Continue Reading