Home Posts tagged Girama Ọba Akinbiyi
Yoruba

Àwọn akẹ́kọ wọlé fún sáà ètò ẹ̀kọ́ kejì nípinlẹ̀ ọ̀yọ́

Ètò ìkẹ́kọ ti bẹ̀rẹ̀ láwọn iléèwe ìjọba àti aládani tó wà nígbogro ìlú ìbàdàn. Akọ̀ròyìn Radio Nigeria tó lọ káàkiri jábọ̀ wí pé àwọn akẹ́kọ ti péjú sọ́gbà iléèwe wọn láàrọ òní pẹ̀lú isẹ́ ìmọ́tótó àyíká iléèwe wọn fún ìkẹ́kọ sáà tuntun. Ó sàkíyèsi wípé ní iléèwe Girama Ọba Akinbiyi tó wà ní Continue Reading