Home Posts tagged Gómìnà Akeredolu
Politics

Gómìnà Akeredolu pè fún àfikún akitiyan láti pinwọ́ ìjínigbé

Gómìnà Oluwarotimi Akeredolu ti ìpínlẹ̀ Òndó ti rọ ọ̀gá àgbà ọlọ́pa nílẹ̀ yí láti túbọ̀ kó àwọn ọlọ́pa àti àwọn oun èèlò ìgbófin ró wá si ìpínlẹ̀ náà láti léè kojú ìwà ìjínigbé tó ti ńdi gbọnmọgbọn nípinlẹ̀ náà. Ó sọ̀rọ̀ àrọwà yi nílu Àkúrẹ́ níbi ìfilọ́lẹ̀ ìgbìmọ̀ tí yíò máà rísí ọ̀rọ̀ ọlọ́pa Continue Reading