Afikun aba isuna oni billionu lona aadota naira ni won ti ka fun Igbakeji nile Igbimo Asofin Ipinle Oyo. Eyi lo waye leyin ti Gomina Seyi Makinde ti fiwe sowo sile igbimo asofin naa ti adari ile, OgbeniAdebo Ogundoyin si kaa to wa beere fun ijiroro ati ibuwolu re. Gegebi Gomina Makinde se so, Continue Reading