-
Ijoba apapo ati ojo WAEC fenuko lori akoko idanwo oniwe mewa
Ijoba apapo ti jo s’adehun pelu ajo to nse kokari idanwo oniwe mewa, WAEC, lori akoko idanwo. Alakoso keji foro Eko nile yi, Ogbeni Emeka Nwajuiba lo soro yi nibi ijabo igbimo amuseya ijoba apapo lori arun Covid-19. Gegebi o se so, o ni adehun ti won se je lori idanwo to nbo lona lori…