Home Posts tagged Ifoma Donu
News Yoruba

Èkàn Nídi Isẹ́ Ìgbóhùnsáfẹ́fẹ́ Pè Fún Ti Túnbọ̀ Gbájúmọ́ Ìròyìn Tóníse Pẹ̀lú Àwọn Arìnrìnàjò

Àwọn tón sisẹ́ ìgbóhùnsáfẹ́fẹ́ ni wọn ti gbà níyànjú láti ma fojú ọmọ̀nìyàn wo ìròyìn àwọn tí wọ́n bá lọ láti ìlú kan sí èkejì, láti jẹ́ káwọn arálu nífẹsí gbígbọ́ rẹ̀. Ọjọgbọn nípa ìmọ̀ isẹ́ ìgbóhùnsáfẹ́fẹ́ ní ilé ẹ̀kọ́ gíga Nnamdi Azikwe nípinlẹ̀ Anambra, ọ̀jọ̀gbọ́n Ifoma Donu ló sọ̀rọ̀ yí Continue Reading