Home Posts tagged Ìjọba ìpínlè Ọ̀yọ́
News Yoruba

Ìjọba ìpínlè Ọ̀yọ́ ṣèlérí atileyin fáwọn ọmọbìnrin káwọn náà lè kópa tó jọ ju láwùjọ.

Didokowo sórí ọmọbìnrin nípa ìpèsè ètò ẹ̀kọ́ tó yé kooro yóò ṣe atileyin tí kò kéré fún wọn nínú gbogbo ìdáwọ́lé wọn nígbà tó bá yẹ kí wọ́n wúlò.   Ìyàwó Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, arábìnrin Tamunominini Makinde ló sọ̀rọ̀ ìyànjú yi fún isami ayajo àwọn ọmọbìnrin lagbaye.  Arábìnrin Makinde Continue Reading