Home Posts tagged Ìjóba ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́
Yoruba

Ìjóba ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ ní àjọsèpọ̀ pẹ̀lú Korea lórí gbígbé ètò ẹ̀kọ́ sórí ìkíni ayélujára

Gómìnà ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́, onímọ̀ ẹ̀rọ Seyi Makinde ti sọpé ìsèjọba òun yo tẹ̀síwájú láti ma sàmúlò òpó ẹ̀rọ ayélujára láti mú kí ètò ẹ̀kọ́ bọ̀ sípò nípinlẹ̀ ọ̀yọ́. Nínú àtẹ̀jáde èyí tí akọ̀wé àgbà sí Gómìnà lórí ọ̀rs ìròyìn, ọ̀gbẹ́ni Taiwo Adisa fisíta nílu’bàdàn, jẹ́ kó di mímọ̀ pé Gómìnà sọ̀rọ̀ Continue Reading