Home Posts tagged Ile-ise olopa
News Yoruba

Ilésẹ́ ọlọ́pa sísọ lójú àwọn tí wọ́n furasí lórí rògbòdìyàn tó wáyé láipẹ yi lágbègbè Ìwó Road.

Alábojútó ilésẹ́ ọlọ́pa nípinlẹ̀ ọ̀yọ́ arábìnrin Ngozi Onadeko ti sísọ lótú àwọn ẹni tí wọ́n furasí mẹ́ta tí wọ́n ni ǹkánse pẹ̀lú rògbòdìyàn tó wáyé lọ́sẹ̀ tó kọjá ládugbò Ìwó Road ìbàdàn. Nígbà tón sísọ, lójú àwọn ẹni wọ̀yí arábìnrin Onadeko sọpé kété tí rògbòdìyàn ọ̀hún wáyé lárin alábojútó Continue Reading