Home Posts tagged Kehinde Ajasa
Yoruba

Ìjọba ró ilé isẹ́ panápaná lágbára nípinlẹ̀ Ọyọ

Gẹ́gẹ́bí ara ìgbésẹ̀ tíjọba àpapọ̀ gbé kalẹ̀, láti pinwọ́ ìsẹ̀lẹ̀ ìjàmbá iná, àtàwọn ìjàmbá miràn lórílẹ̀èdè yí, ilésẹ́ panápaná nílẹ̀ yí ti ra àwọn on èlò sí ẹ̀ka ọ́fìsì rẹ̀ nípinlẹ̀ ọyọ pllú àfikún àwọn ọkọ̀ ńláńlá méjì tín pa iná. Olùdarí àgbà fún ilésẹ́ náà, Alhaji Liman Ibrahim ló sọ̀rọ̀ Continue Reading