Home Posts tagged Mr Mukar Mohammed
Yoruba

Ìjọba Àpapọ̀ Sún Àsẹ Máà Sisẹ́ Látilé Síwájú Si

Ìjọba àpapọ̀ orílẹ̀dè yíì ti sún àsẹ máà sisẹ́ rẹ̀ wá látilé fáwọn òsìsẹ́ ọba tó wá lákàsọ̀ kejì la sísàlẹ̀ síwájú si, gẹ́gẹ́bí ara ìgbésẹ̀ láti dènà ìtànkélẹ̀ kòkòrò àrùn covid-19 ẹlẹkeji nílẹ̀ Nàijírìa. Gẹ́gẹ́ bálámojútó tó wà fọ́rọ̀ kòkòrò àrùn náà, nílẹ̀ yíì, ọ̀gbẹ́ni Mukhtar Mohammed sesọ Continue Reading