Awon onimo nipa eto ilera ti gbawon olugbe ipinle Oyo niynaju lati maa sora se kiwon si mu awon ilana atale eyi toun fun didena itankale kokoro arun COVID-19 lokunkundun. Lakoko ti won b’oniroyin soro lori ibesile arun onigbameji to waye lenu loolo yii, niwon gbawon niyanju naa, okan lara won, Continue Reading