Home Posts tagged mùsùlùmí
News Yoruba

Àwọn Mùsùlùmí jékèjádò orílẹ̀èdè ti tújáde lọ́pọ̀ yanturu fún ìrun yídì ayẹyẹ ọdún iléyá tón lọ lọ́wọ́.

Àwọn èèkàn ọmọ ilẹ̀ yíì, àwọn olósèlú àtàwọn tó dipò àsẹ mú nílẹ̀ yíì, nílu ìbàdàn ti kórajọpọ̀ sí ibùdó ìkírun tó wà ládugbò Agodi láti kí ìrun ọdún iléyá fún tọdún yíì. Ibùdó ìkírun náà làwọn olùjọ́sìn péjú sí, pẹ̀lú onírunru asọ lọrùn wọn, èyí tó ń sàfihàn ayẹyẹ ọdún iléyá. Lára àwọn èèyàn Continue Reading
Yoruba

Gómìnà ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ ńfẹ́ káwọn èyàn àwùjọ túnbọ̀ gba àláfìa láye

Gómìnà ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́, onímọ̀ ẹ̀rọ Seyi Makinde ti kí gbogbo àwọn mùsùlùmí nípinlẹ̀ ọ̀yọ́ kú oríre ọjọ́ ìbí òjísẹ́ ńlá Muhammad.  Nínú àtẹ̀jáde èyí tí akọ̀wé àgbà lórí ọ̀rọ̀ ìròyìn sí Gómìnà, ọ̀gbẹ́ni Taiwo Adisa fisíta, Gómìnà rọ àwọn Mùsùlùmí láti gbé ẹ̀wù ìfẹ́, àláfìa, ìfiraẹnijì wọ̀. Gómìnà Makinde tún fi àsìkò ọdún yi láti […]Continue Reading