Home Posts tagged ọ̀gá àgbà pátápátá fọ́rọ̀ ọlọ́pa nílẹ̀ yíì
Yoruba

Gómìnà Seyi Makinde Sèlérí Láti Mú Inú Ẹbí Àwọn Ọlọ́pa Tíwọ́n Sekúpa Nínú Ìfẹ̀húnúhàn Dùn

Gómìnà ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, Onímọ̀ẹ̀rọ Seyi Makinde ti sèlérí pé òun yóò ridájú pé òun dun ẹbí àwọn ọlọ́pa tíwọ́n sekúpa lákokò ìfẹ̀húnúhàn fífòpinsí ikọ̀ SARS, nínú tóun yóò sì sàtúnse sáwọn ilé-isẹ́ ọlọ́pa tíwọ́n bà jẹ́. Níbi ìpàdé àláfìa kan tí Gómìnà se pẹ̀láwọn ọ̀gá àgbà ilé-isẹ́ ọlọ́pa ìpínlẹ̀ Continue Reading