Home Posts tagged ọ̀gbẹ́ni Ọladeji Akinọla
Yoruba

Ẹgbẹ́ CIIN ti ní Adarí Tuntun

Ẹgbẹ́ àwọn akọ́sẹ́mọsẹ́ lórí adójútófo nílẹ̀ yí CIIN ẹ̀ka tìpińlẹ̀ ọ̀yọ́ ti búra fún àwọn ọmọ ìgbìmọ̀ tuntun. Ètò yí tó wáyé níbi ayẹyẹ ìfàmìẹ̀yẹ dáni lọ́lá àti ìgbaniwọlé ọlọ́lọọdún wọn tó wáyé nílu ìbàdàn ni wọ́n ti búra fún ọ̀gbẹ́ni Ọladeji Akinọla gẹ́gẹ́bí alága àti àwọn ọmọ ìgbìmọ̀ mẹ́jọ Continue Reading