Home Posts tagged Òjò
Yoruba
Òjò alágbára tó rọ̀ nílu’bàdàn lána òde yi ti ba àwọn ilégbe iléwe tófimọ́ òpó iná jẹ́. Akọ̀ròyìn ilésẹ́ Radio Nigeria tó tọpinpin ìsẹ̀lẹ̀ náà, jábọ̀ pé òrùlé àwọn ilégbe kan lágbugbò Agbowó àti orogún ni ìjì ọ̀hún gbé lọ. Yàtọ̀ fún àwọn ìgì tó wọ́lu ojú òpópónà, àwọn irinsẹ́ tón mú iná wọlé ilésẹ́ […]Continue Reading
Load More