Home Posts tagged Shuaibu Labaran
Yoruba

Ilé Ẹjọ́ Fi Asájú Ikọ̀ IPOB Síhamọ́ Di Ọjọ Kẹrìndínlọ́gbọ̀n Osù Tónbọ̀

Ètò ìgbẹ́jọ asíwájú kan fún àwọn èyàn ilẹ̀ Biafra, IPOB, Nnamdi Kanu ẹni tọ́wọ́ àwọn agbófinro tún tẹ̀ lana, ni wọ́n yo tlsíwájú láti ma gbọ́ ìgbẹ́jọ́ rẹ̀ lọ́jọ́ kẹrindinlọgbọn osù tón bọ̀. Nígbàtí ètò ìgbẹ́jọ́ bẹ̀rẹ̀, nílé ẹjọ́ gíga nílu Abuja, agbẹnusọ fún ìjọba Shuaibu Labaran bẹ̀bẹ̀ pé kí Continue Reading