Home Posts tagged Sunday Makinde
Yoruba

Ilé isẹ́ ọmọ ogun ojú òfurufú bèèrè fún àtìlẹyì aráàlu lórí gbígbógun ti ètò àbò tó mẹ́hẹ.

Ilé isẹ́ ọmọ ogun ojú òfurufú ilẹ̀ yíì, NAF, ti rọ àwọn èèyàn láti máà sàtìtilẹyìn fákitiyan àwọn òsìsẹ́ aláàbo gbogbo, kópin lè dé bá àbò tó mẹ́hẹ yíká ilẹ̀ Nàijírìa. Ọga ọmọ ogun ojú òfurufú , Sunday Makinde ló pàrọwà yíì lẹ́yìn ètò ìsìn alájùmọ̀se kan towa ye láti fi sàmì ayẹyẹ ọdún Continue Reading