Home Posts tagged Tolulọpẹ Arotile
Yoruba
Wọ́n ti sin òkú arábìnrin àkọ́kọ́ tó wa báàlu ìjagun, Tolulọpẹ Arotile tó papòdà lọ́jọ́ kẹrìnlá osù keje ọdún yi. Ayẹyẹ ìsìnkú lówáyé ní ilé ìsìnkú àwọn olóògun tó wà lágbègbè pápákọ̀ òfurufún Nnamdi Azikiwe Abuja, lábẹ́ àbò tó gbópọn, ìwọ̀nba àlejò àti mọ̀lẹ́bí nìkan ni wọ́n gbà láye wọ ilé ìsìnkú náà. Ìròyìn sọpé […]Read More...
Load More