Home Posts tagged wọn darandaran
Yoruba

Gómìnà Makinde sekìlọ̀ fáwọn èèyàn tó ń gbìyànjú láti domi àláfìa ọ̀yọ́ rú

Gómìnà ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́, onímọ̀ẹ̀rọ Seyi Makinde ti sèkìlọ̀ fáwọn èèyàn láti yàgò kúrò nídi àwọn ìgbésẹ̀ kan, èyí tó lè yọrísí fífi tìpá tikuuku yo yan kan kúrò nípò tàbí léwọn kúrò nípinlẹ̀ ọ̀yọ́. Ìkìlọ̀ yíì ló wáyé níbamu pẹ̀lú dàrúdápọ tó wáyé láàrin àwọn àgbẹ̀ àtàwọn darandaran kan lágbègbè Continue Reading