News Yoruba

Ajo DPR Yoo Tepelemo Pipa Owo Sapo Ijoba

Eka to n ri soro epo petirolu, DPR, ti soo dii mimo pe won to ni kaare lori sise amulo ilana ti yoo mu ona ipawo wole sapo ijoba apapo gberu.

Oludari eka naa, Ogbeni Sarki Auwalu lo soro yi di mimo ninu atejade to fi sita nilu Eko.

Ogbeni Auwalu salaye pee eka DPR, to je ekan lara eka to n pawo sapo ijoba ti fi owo to le ni billionnu kan ati oodunrun millionu dollar sowo sapo asunwon ijoba apapo latari owo ti won pa leka epo robi ati arere gaasi.

O salaye wi pe won se aseyori yi nipase eto atunto ati jijara mose lati pawo sapo ijoba.

Oga agba eka naa tun salaye wipe kii se ara ojuse ajo naa lati gba ijoba nimoran pe ki won ma ya owo lodo awon ajo ayanilowo lagbaye.

OluremiI/Salaudeen

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *