News Yoruba

Ajo To Nse Kokari Ina Oba Seleri Agbega Eka Naa.

Ajo to n se kokari oro ina ob anile yi NERC ti salaye igbiyanju lori tito pinpin irufe ina to n he pipese fara ilu.

Alamojuto ajo naa leke isuna ati akoso Ogbeni Nathan Shatti lo soju abe oro yi niko lasiko ipade ilu.

Ogbeni Shatti salaye wipe ajo naa ti mu agbega ba ona ti adinku yio fib a idekureku ina oba pelu alaye wipe o seese ki igbiyanju naa lo die-die.

O tenumo pe, o pondandan ki ile kookan ni ero to n ka ina oba laarin ojo mewa ti won ba ti san owo fun ero naa, o wa tenumo pe ki eni to ba fe gba ero to n ka ina oba beere pe se ero naa w anile ki won to lo sanwo.

Ipade naa lo waye pelu awon asoju ileese to n pin ina oba, ajo Disco, eka to n pin ero to n ka ina oba ati gbogbo awon toro naa gberu.

Aluko/Salaudeen

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *