Lilo onte iforukosile ni ko ni pa dandan mo bayi fawon ile ise.

Akowe agba ajo to n risi eto iforukosile awon ile ise nile yi, Alhaji Garba Abubakar lo soro naa nilu Abuja ti agbenuso ajo ohun Ogbeni Rasheed Mahe si buwolu leyin iside ipade apero olojo kana won oni bara atawon eni oro kan min.

Alhaji Abubakar Saleya pe lara awon nkan to wa ninu ofin tuntun ajo naa ni pinpin iwe igbawole awon ile ise atawon liana min.

Akowe agba ajo CAC wa tenumo afenuko re lori agbekale ohun amuse liana atunto ajo naa fun eto iforuko sile to moyan lori.

Seyifunmi Olarinde/Ayodele Olaopa

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *