Home Posts tagged BECAN
News Yoruba

Àwọn Tọ̀rọkàn Bèrè Fún Àgbende Ètò Ẹ̀kọ́ Tóyèkoro

Bí orílẹ̀dè se ń darapọ̀ mọ́ àwọn orílẹ̀dè àgbéyé tókù láti sàmì àyájọ́ àwọn olùkọ́, àwọn tọ́rọkàn lẹ́ka ètò ẹ̀kọ́ tí rọ ìjọba nígbogbo ẹ̀ka láti se àtúngbédìde ètò ẹ̀kọ́ tó yéè koro. Àarẹ ẹgbẹ́ àwọn òsìsẹ́ lẹ́ka ètò ẹ̀kọ́ alákọbẹ̀rẹ̀ BECAN, , arábìnrin Dorcas Abuge sọ èyí nígbà tó ńbá Continue Reading