Home Posts tagged ìjàmbá iná
Yoruba

Awọn asòfin pèfún ìpèsè ẹ̀rọ ítani lólobó fún ìjàmbá iná

Ilé ìgbìmọ̀ asòfin kejì ti rọ ilé-isẹ́ panápaná ìjọba àpapọ̀ látiridájú pé, wọ́n pèsè àwọn ẹ̀rọ tí yóò máà ta àwọn aráàlu lólobó tísẹ̀lẹ̀ ìjàmbà iná bá fẹ́ wáyé yíká àwọn ọjà tónbẹ lórílẹ̀dè yíì, láti dábobo ẹ̀mí àti dúkia aráàlu àti láti dènà ìsẹ̀lẹ̀ ìjàmbà iná lemọ́lemọ́ nílẹ̀ Nàijírìa. ọ̀rọ̀ Continue Reading
Yoruba

Àjọ INEC fọkàn àwọn ẹgbẹ́ òsèlú kan balẹ̀ lórí ìsẹ̀lẹ̀ ìjàmbá iná tó wáyé

Àjọ elétò ìdìbò ilẹ̀ yí, INEC, ti ní ìsẹ̀lẹ̀ ìjàmbá iná tó wáyé lápá ibìkan nílé isẹ́ nà tó wà nílu Àkúrẹ́ kò ní nípa lórí ètò ìdìbò Gómìnà tí yio wáyé ní ọjọ́ kẹwa osù tó ńbọ̀ nípinll Òndó. Alága ẹ̀ka tó wà fún ìdánilẹ̀kọ olùdìbò nínú àjọ ọ̀ún, ọ̀gbẹ́ni Festus Okoye ló sọ̀rọ̀ […]Continue Reading