Home Posts tagged Ipinle Oyo
Yoruba
Bí àgbáyé se ń sàmíì àyájọ́ ọjọ́ àwọn olùkọ́ adarí ilé ìgbìmọ̀ asòfin ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́, ọ̀gbẹ́ni Adebọ Ogundoyin ti sàpèjúwe àwọn olùkọ́ gẹ́gẹ́ bí igilẹ́yìn ọgbà ìdàgbàsókè àwùjọ tí ó sepàtàkì láti máà mọrírì nígbàgbogbo. Nínú ọ̀rọ̀ ìkínni rẹ̀ fún àyájọ́ àwọn olùkọ́ fún tọdún yíì, ọ̀gbẹ́ni Read More...
Yoruba
Ilé ìgbìmọ̀ asòfin ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ ti sèlérí láti tẹ̀tíwájú nínu sísa ipá rẹ̀ lórí dídábòbò ètò àwọn ọmọbíbí ìpínlẹ̀ yí nípasẹ̀ gbígbé òfin tí yo mú kígbàdẹrùn fáràlú kalẹ. Alága ìgbìmọ̀ tón rírí ọ̀rọ̀ ilẹ̀ òkèrè nílé asòfin, ọ̀gbẹ́ni Seyi Adisa ló sèlérí yi lásìkò tón kópa lórí ètò ilésẹ́ Premier FM tí wọ́n pè […]Read More...
Yoruba
Gómìnà ìpínlẹ̀ Ọyọ, onímọ̀ ẹ̀rọ Seyi Makinde sọpé ètò ìsèjọba tóun ńléwájú rẹ̀ kóní tẹ̀tì láti gùnlé àwọn ìpinnu èyí tí yóò fẹsẹ̀ ìdàgbàsókè tóò lórin múlẹ̀ nípinlẹ̀ Ọyọ. Ó sọ èyí nígbà tó ńgba àbọ̀ ìwádi ìgbìmọ̀ ẹlẹ́ni méje, èyítí ìsèjọba rẹ̀ gbé kalẹ̀ láti wòye sí oníruru ìpèníjà tó ńkojú ìpínlẹ̀ yíì, lọ́fìsì […]Read More...
Load More