Home Posts tagged Nàijírìa
News Yoruba
Olórí ọmọ ológun Ibrahim Attahiru, sọpé àfojúsùn òhun ni tiridájúpé òpin débá ìwà ìgbésùmọ̀mí kóun gbogbo sì padà bọ̀ sípò lápá ìlàa-oorun ilẹ̀ yíì àtorílédé Nàijírìa lápapọ̀. Ọgagun àgbà Attahiru sọpé ikọ̀ ọmọlóju yóò fọwọ́sowọ́pọ̀ pẹ̀lú àwọn ikọ̀ ọmọlógun Camaroon àti Chaad nídi fífòpin sí ìwà ìgbésùmọ̀mí. Ó sọ̀rọ̀ yíì lásìkò tó ńbá ikọ̀ ọmọlógun […]Read More...
News Yoruba
Àwọn Gómìnà nípinlẹ̀ mẹ́rìn dín lógún lábẹ́ àsía ìgbìmọ̀ nílẹ̀ Nàijírìa, ni wọ́n ti sọpé àwọn kokoo, àwọn ǹkan ìrọ̀rùn tó wà fún àwọn tó kudiẹ káto fún láwùjọ pamọ́ lásìkò tí fífi òpin sí ìtànkálẹ̀ àrùn covid-19 le dandan.  Àwọn Gómìnà ló sọ̀rọ̀ yí di mímọ̀ nínú àtẹ̀jáde èyí tí olórí lẹ́ka tón mójútó […]Read More...
Yoruba
Orólẹ̀èdè wa Nàijírìa, ilẹ̀ olóminira Niger àti orílẹ̀èdè Chad ti ńsisẹ́ lórí àkànse ètò láti fi se àtúnse ibùdó adágún odò Chad, kí ètò ìgbáyégbádùn ba lè wà fáwọn èèyàn tó wà lágbègbè adágún odò na. Ọga àgbà àjọ kan tí wọ́n ń pè ní National Agency for the great green wall, ọ̀mọ̀wé Bukar Hassan […]Read More...
Load More