Home Posts tagged NSITF
Yoruba
Ilé isẹ́ àarẹ ti késí ẹgbẹ́ àwọn òsìsẹ́ T.U.C láti sẹ́wẹ́lé ìfẹ̀hònú hàn káàkiri ilẹ̀ yí tí wọ́n fẹ́ gùnlé lórí bí àarẹ Muhammadu Buhari ti se káwọ́ gbera lórí oníruru ìwà àjẹbánu tí wọ́n tú síta láipẹ yí. Àrọwà yi ni ó wà nínú àtẹ̀jáde láti ọwọ́ olùrànlọ́wọ́ pàtàkì sí àarẹ lórí ọ̀rọ̀ ìròyìn […]Read More...
Load More