Home Posts tagged Onímọ̀ ìsègùn
News Yoruba

Onímọ̀ ìsègùn sàtẹnúmọ́ ìdí fún ìtọ́jú ojú

Àwọn ọmọ olẹ̀ yí ni wọ́n ti gbà lámọ̀ràn láti máà sàyẹ̀wò ojú wọn ó kéré tán léèkan lọ́dún láti léè tètè kẹ́ẹ̀fín bí ojú bá ní ìpèníjà. Olùtọ́jú ojú tíì tún se igbákejì ọ̀gá àgbà lẹ́ka olùtọ́jú aláisan nílé ìwòsàn ẹ̀kọ́sẹ́ ìsègùn U.C.H., arábìnrin Abiọla Agatha ló fàmọ̀nràn yi Continue Reading