Home Posts tagged Saudi Arabia (Page 2)
News Yoruba

Ilẹ̀ Saudi Arabia se tán láti fààyè ètò ẹ̀kọ́ ọ̀fẹ́ sílẹ̀ fáwọn akẹ́kọ́ọ̀ ilẹ̀ Nàijírìa.

Ìjọba orílẹ̀dè Saudi Arabia ti sọ́ọ̀di mímọ̀ pé, òun yóò fún bi irinwo àwọn akẹ́kọ́ọ̀ ilẹ̀ Nàijírìa létò ẹ̀kọ́ ọ̀fẹ́, tófimọ́ fífiàyè ètò ẹ̀kọ́ ọ̀fẹ́ sílẹ̀ fáwọn akẹ́kọ́ọ̀ ilẹ̀ adúláwọ̀ tó lé lẹ́gbẹ̀rún mẹ́fà lọ́dọọdún. Èyí ló jẹyọ nínú àtẹ̀jáde kan, Continue Reading